Uploaded by oduanation007 on Mar 30, 2008
Olóògbé Obáfẹmi Awólọwọ̀ (1909 - 1987), olósèlú, ọmọ orílẹ̀èdè Nàìjíríà lati ẹ̀yà Yorùbá. Awólọwọ̀ jẹ́ olórí fún àwon omo ilé Yorùbá àti òkan nínú àwon olósèlú pàtàkì ni orílè èdè Nàìjíríà.
A bí ni ojó kefà osù keta ọdún 1909 ni Ikénne ni ìpínlè Ogun. Omo àgbé tí ó fi isé àti ogun isé so ara rè di omòwe, Awólówó ló ilé èkó Anglican àti Methodìst ni Ikénne àti ni Baptist Boys' High School ni Abéòkúta. Lèyìn rè ó ló sí Wesley College ni Ibàdàn tí ó fi ìgbà kan jé olùìlú Agbègbè Iwó Oòrun Orílé èdè Nàìjíríà láti ba di Olùko.
Ní ọdún 1934 , ó di olùtajà àti oníròyìn. O se olùdarí àti alákóso Egbé Olùtajà Awon Omo Nàìjíríà (Nigerian Produce Traders Association) àti àkòwé gbogbogbo Egbé Awon Awako Igb'eru Omo Ilè Nàìjíríà (Nigerian Motor Transport Union). Awólówó tèsíwájú nínú èkó rè, ó sí gbà ìwé erí kékeré ni ọdún 1939, kí ó tó ló láti gbà ìwé erí èkó gíga nínú ìmò owó ni ọdún 1944.
Igbà yí nà ló tún jé olóòtú fún ìwé ìròyìn Nigerian Workers (Osisé Omo Ilè Nàìjíríà). Ní ọdún 1940 ó di àkòwé Egbé Odò Awon Omo Ilè Nàìjíríà (Nigerian Youth Movement) èka Ibàdàn, ibi ipò yí ni ó tí s'olori ìtiraka láti se àtúnse Igbìmọ́ Aláse Idámòràn Fún Awon Omo Ibàdàn (Ibàdàn Native Authority Advisory Board) ni ọdún 1942.
Ni ọdún 1944 o lo si ilu Londonu lati ko eko ninu imo ofin be ni o si se idasile Egbe Omo Oduduwa. Leyin igba to pari eko re ni ọdún 1947 o dari pada wale lati wa di agbejoro ati akowe agba fun Omo Egbe Oduduwa. Leyi ọdún meji, Awolowo ati awon asiwaju Yoruba yioku se idasile Egbe Oselu Action Group eyi ti o bori ninu ibo ọdún 1951 ni Agbegbe Iwo Oorun Ile Naijiria.
Larin ọdún 1951-54 Awolowo je Alakoso Fun Ise Ijoba ati Ijoba Ibile, o si di Olori Ijoba Agbegbe Iwo Oorun Ile Naijiria ni ọdún 1954 leyin atunko Iwe Igbepapo Ati Ofin (constitution).
Gege bi Olori Ijoba Agbegbe Iwo Oorun Ile Naijiria, Awolowo se idasile eko ofe fun gbogbo odo lati ri pe moko moka gba le ka. Ni igba ti orile ede Naijiria di olominira ni ojo kinni osu kewa ọdún 1960, Awolowo di Olori Alatako Oselu (Opposition Leader) si ijoba Abubakar Tafawa Balewa ati Aare Nnamdi Azikwe ni Ilu Eko. Aiko enu larin ohun ati Samuel Ladoke Akintola to dipo re gege bi Olori Ijoba ni Agbegbe Iwo Oorun ni o fa jagidijagan ti o sele ni ọdún 1962.
Ni ọdún yi ni osu kokanla re sini Ijoba Apapo ile Naijiria fi esun kan Awolowo pe o dote lati doju ijoba bole. Leyin igbejo to gba osu mokanla, ile ejo da Awolowo ati awon egbe oselu re mejidinlogbon lebi esun idote, won si ran won lo si atimole fun ọdún mewa. ọdún meta pere ni o lo ni ile ewon ni ilu Calabar ti ijoba ologun Yakubu Gowon si fi sile ni ojo keta osu kejo ọdún 1966. Leyin eyi Awolowo di Alakoso Ijoba Apapo fun Oro Okowo. Ni ọdún 1979 Awolowo se idasile Egbe Oselu Imole.
Obafemi Awolowo se alaisi ni ojo aiku ojo kesan osu karun ọdún 1987 ni ilu Ikenne. Leyin iku Awolowo Ijoba Apapo yi oruko Ile Eko Giga Ile-Ife si Obafemi Awolowo University. Be si aworan Awolowo wa lori owo ogorun naira fun eye gbogbo ohun to se fun idagbasoke ile Yoruba ati orile ede Naijiria lapapo.
Link to this comment:
Uploader Comments (oduanation007)
All Comments (13)
-
i like 'am so. Na sweet
DjKalil 2 years ago
-
hmmmm...daddy AWO...we beleive u lives on
K1ofASIA 2 years ago
-
awolowo lives on , good man ,great leader of men and an utilitarian servant to humanity
tessyfat 2 years ago
-
awolowo lives for ever in the minds of humanity bcos of his utilitarian services to the masses
tessyfat 2 years ago
-
Afenifere for life. Awolowo, a great man indeed and a blessing to the Yoruba race, and Nigeria. Born 1909, a century apart from America's Abraham Lincoln, born in 1809. Both men Rosicrucians.
Happy 100 years b'day Papa Awo.
Naija Must Sweet Again!!!
tosinmusik 2 years ago
-
Afenifere for life!!!
Awo, a great man indeed; a blessing to the Yoruba race. Born in 1909, a century apart from Abraham Lincoln, born 1809. Both men Rosicrucians.
Happy 100 years b'day Papa Awolowo.
A man never to be forgotten in the minds of well-meaning Nigerians, just as Lincoln keeps resurfacing in the American contemporary world.
Naija Must Sweet Again!!!
tosinmusik 2 years ago
6:41Are they waking up? 2 of 2by Okoroman16,773 views
9:35Babangida and Vatsa (Part 2 of 6)by mrgeronimo584,041 views
8:51OJUKWU's SPEECH THE BIAFRANS DURRING THE NIGERI...by jointznjamzEnt40,824 views
10:04CHIEF HUBERT OGUNDE COLLECTIONS(audio)1/3by EgbaAlake26,631 views
11:22Akintola_Speech_Part_2.wmvby bestmanyt5,354 views
1:32Last Days Of Abachaby Embassytelecom231,437 views
7:56Nigeria: What changed? Alhaji Sir Abubakar Tafa...by Okoroman17,735 views
2:13Sarduana (1).mp4by MrOlekan9,565 views
15:02Iga Obaby yorubaactors1,967 views
2:24Nigeria Coup Video, Abacha Coupby abiez189,594 views
10:57Chief Hubert Ogunde-Aiye(Audio)by EgbaAlake53,214 views
10:00Baba Ogunde African Wisdom. Pt 3by OgundeWisdom3,794 views
9:08DUTY TO NIGERIA by CHIEF OBAFEMI AWOLOWO and C...by ladisoyode24,713 views
5:35Oduduwaby yorubaactors49,709 views
11:00IDI AMIN pt.8by blackson197773,735 views
1:05Tafawa Balewa in London after Nigeria declares ...by demonteufel55,473 views
13:13Part 2 of 4: Journey to Nationhood | The Coloni...by 419Positive8,433 views
6:09So you don't believe in miracles... - watch thi...by unendingsearch1,116,728 views
4:13Exclusive interview with Olusegun Obasanjo - 29...by AlJazeeraEnglish150,139 views
- Loading more suggestions...
I wonder who could nt hv ruled those countries "successfully", seeing dt they are organized: Do u know how many races, ethnic & party groups there are in those countries, yet they moved on? As defacto Vice to Gowon, Chief Awolowo's failure to instigate grandstandings d type he did in d West baffles imagination. He learned nothing 4rm d "Carpet-crossing" in the then W/Region Leg/Election & his 20 pounds advice was a script. Forget d Russians! One must love a ppl 2 affect them. Love 1st!
igbos27 2 years ago
I'm not sure what you mean by 'grandstanding', but you're right: Love 1st.
Chief Obafemi Awolowo indeed loved his people and Nigeria in general. Perhaps you're one of his free-education beneficiary like most elite igbos are.
oduanation007 2 years ago
@igbos27 You are quite correct. Awo is simply one of the greatest across the board. However his inability to capture the imagination of the others is certainly to be regretted. Perhaps it is more of a reflection of the severe undereducation of the Nigeria of the period or simply peronal failings -we will never know. But I suspect that Nigeria will not have been hurt if men like him had executive power over the whole territory. Things will certainly have been different -a bit at least.
korupshun1 2 years ago
Awolowo was a product of his time. He served his country during turbulent times when ethnocetricity was rife and sectional self interests were the order of the day. Ojukwu definitely wanted to break away and there is nothing anyone else could have done about that.
In hindsight though, I really wished the Western Region took advantage of the initial Biafran chaos to declare their own indepenhdence from the clutches of Northern domination. We missed a good window of opportunity.
oduanation007 2 years ago